Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín yóo gbé wolii kan dìde tí yóo dàbí mi láàrin yín, tí yóo jẹ́ ọ̀kan ninu àwọn arakunrin yín, òun ni kí ẹ máa gbọ́ràn sí lẹ́nu.

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:15 ni o tọ