Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 18:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni ninu yín kò gbọdọ̀ fi ọmọ rẹ̀ rú ẹbọ sísun, kì báà ṣe ọmọ rẹ̀ obinrin tabi ọkunrin. Ẹnikẹ́ni kò sì gbọdọ̀ máa wo iṣẹ́ kiri tabi kí ó di aláfọ̀ṣẹ tabi oṣó;

Ka pipe ipin Diutaronomi 18

Wo Diutaronomi 18:10 ni o tọ