Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 17:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ̀dà àwọn òfin yìí máa wà pẹlu rẹ̀, kí ó sì máa kà á ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀; kí ó lè kọ́ láti bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun rẹ̀, nípa pípa gbogbo òfin ati ìlànà wọnyi mọ́, kí ó sì máa tẹ̀lé wọn;

Ka pipe ipin Diutaronomi 17

Wo Diutaronomi 17:19 ni o tọ