Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 17:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín, tí ẹ bá gbà á, tí ẹ sì ń gbé inú rẹ̀, tí ẹ bá wí nígbà náà pé, ‘A óo fi ẹnìkan jọba lórí wa gẹ́gẹ́ bí àwọn orílẹ̀-èdè yòókù tí wọ́n yí wa ká,’

Ka pipe ipin Diutaronomi 17

Wo Diutaronomi 17:14 ni o tọ