Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 17:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹjọ́ tí wọ́n bá dá fun yín ni kí ẹ gbà, kí ẹ sì tẹ̀lé gbogbo ìlànà tí wọ́n bá là sílẹ̀. Ẹ kò gbọdọ̀ yà sí ọ̀tún tabi sí òsì ninu ẹjọ́ tí wọ́n bá dá fun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 17

Wo Diutaronomi 17:11 ni o tọ