Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ meje ni ẹ óo fi se àsè yìí fún OLUWA Ọlọrun yín níbi tí OLUWA bá yàn pé kí ẹ ti máa jọ́sìn, nítorí OLUWA Ọlọrun yín yóo bukun gbogbo èso yín, ati gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ yín, tóbẹ́ẹ̀ tí ẹ óo láyọ̀ gidigidi.

Ka pipe ipin Diutaronomi 16

Wo Diutaronomi 16:15 ni o tọ