Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà, ẹ óo ṣe àsè àjọ ọ̀sẹ̀, tíí ṣe àjọ̀dún ìkórè fún OLUWA Ọlọrun yín; pẹlu ọrẹ àtinúwá. Ẹ óo mú ọrẹ náà wá bí OLUWA Ọlọrun yín bá ti bukun yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 16

Wo Diutaronomi 16:10 ni o tọ