Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 15:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹ óo ṣe máa ṣe ìdásílẹ̀ náà nìyí: ẹnikẹ́ni tí aládùúgbò rẹ̀, tíí ṣe arakunrin rẹ̀, bá jẹ ní gbèsè kò ní gba ohun tí aládùúgbò rẹ̀ jẹ ẹ́ mọ́, nítorí pé, a ti kéde ìdásílẹ̀ tíí ṣe ti OLUWA.

Ka pipe ipin Diutaronomi 15

Wo Diutaronomi 15:2 ni o tọ