Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Má jẹ́ kí ó ni ọ́ lára láti dá a sílẹ̀ kí ó sì máa lọ lọ́fẹ̀ẹ́, nítorí pé, ìdajì owó ọ̀yà alágbàṣe ni ó ti fi ń sìn ọ́, fún odidi ọdún mẹfa. Bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ ṣe, kí OLUWA Ọlọrun yín lè bukun ohun gbogbo tí ẹ bá ń ṣe.

Ka pipe ipin Diutaronomi 15

Wo Diutaronomi 15:18 ni o tọ