Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí wọ́n bá ta arakunrin yín lẹ́rú fun yín, kì báà jẹ́ ọkunrin tabi obinrin, tí ó bá ti jẹ́ Heberu, ọdún mẹfa ni yóo fi sìn yín. Tí ó bá di ọdún keje, ẹ gbọdọ̀ dá a sílẹ̀, kí ó sì máa lọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 15

Wo Diutaronomi 15:12 ni o tọ