Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 14:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹlẹ́dẹ̀, lóòótọ́ ó ní ìka ẹsẹ̀, ṣugbọn kì í jẹ àpọ̀jẹ, nítorí náà, ó jẹ́ aláìmọ́ fun yín. Ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹran ara wọn, bẹ́ẹ̀ ni ẹ kò gbọdọ̀ fara kan òkú wọn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 14

Wo Diutaronomi 14:8 ni o tọ