Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 14:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi owó náà ra ohunkohun tí ọkàn yín bá fẹ́, ìbáà ṣe akọ mààlúù, tabi aguntan, tabi ọtí waini, tabi ọtí líle, tabi ohunkohun tí ọkàn yín bá ṣá fẹ́. Ẹ óo jẹ ẹ́ níbẹ̀ níwájú OLUWA Ọlọrun yín, ẹ óo sì máa yọ̀, ẹ̀yin ati ìdílé yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 14

Wo Diutaronomi 14:26 ni o tọ