Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 14:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn pé kí ẹ ti máa sin òun ni kí ẹ ti jẹ ìdámẹ́wàá ọkà yín, ati ti ọtí waini yín, ati ti òróró yín, ati àkọ́bí àwọn mààlúù yín, ati ti agbo ẹran yín; kí ẹ lè kọ́ láti bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun yín nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Diutaronomi 14

Wo Diutaronomi 14:23 ni o tọ