Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ wádìí ọ̀rọ̀ náà. Bí ó bá jẹ́ pé òtítọ́ ni, tí ó sì dáa yín lójú pé ohun ìríra bẹ́ẹ̀ ti ṣẹlẹ̀ láàrin yín,

Ka pipe ipin Diutaronomi 13

Wo Diutaronomi 13:14 ni o tọ