Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:30 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹ ṣọ́ra, kí ẹ má baà ṣìnà, lẹ́yìn tí Ọlọrun bá ti pa wọ́n run tán, kí ẹ má baà bèèrè pé, ‘Báwo ni àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi ṣe ń bọ àwọn oriṣa wọn? Kí àwa náà lè máa ṣe bẹ́ẹ̀.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:30 ni o tọ