Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wó gbogbo pẹpẹ wọn lulẹ̀, ẹ fọ́ gbogbo òpó wọn, ẹ dáná sun àwọn ère oriṣa Aṣera wọn, ẹ gé gbogbo àwọn ère oriṣa wọn lulẹ̀, kí ẹ sì pa orúkọ wọn rẹ́ kúrò níbẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:3 ni o tọ