Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn ẹ lè pa iye ẹran tí ó bá wù yín, kí ẹ sì jẹ ẹ́ níbikíbi tí ẹ bá ń gbé, gẹ́gẹ́ bí OLUWA Ọlọrun yín bá ti bukun yín tó. Ẹni tí ó mọ́, ati ẹni tí kò mọ́ lè jẹ ninu ẹran náà bí ìgbà tí eniyan ń jẹ ẹran ẹtu tabi ti àgbọ̀nrín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 12

Wo Diutaronomi 12:15 ni o tọ