Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí OLUWA ti búra fún àwọn baba yín pé òun yóo fún wọn ati àwọn arọmọdọmọ wọn. Ilẹ̀ tí ó lọ́ràá tí ó sì ní ẹ̀tù lójú tí ó kún fún wàrà ati oyin.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:9 ni o tọ