Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

ati ohun tí ó ṣe sí Datani ati Abiramu, àwọn ọmọ Eliabu, ọmọ ọmọ Reubẹni. Ẹ ranti bí ilẹ̀ ti lanu, tí ó sì gbé wọn mì ati àwọn ati gbogbo ìdílé wọn, ati àgọ́ wọn, ati gbogbo iranṣẹ ati ẹran ọ̀sìn wọn, láàrin gbogbo Israẹli.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:6 ni o tọ