Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti ohun tí ó ṣe sí àwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Ijipti ati sí àwọn ẹṣin wọn ati kẹ̀kẹ́ ogun wọn; bí ó ti jẹ́ kí omi Òkun Pupa bò wọ́n mọ́lẹ̀ nígbà tí wọ́n ń le yín bọ̀, ati bí OLUWA ti pa wọ́n run títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:4 ni o tọ