Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Òkè Gerisimu ati òkè Ebali wà ní òdìkejì Jọdani, ní ojú ọ̀nà ní ìhà ìwọ̀ oòrùn, ní ilẹ̀ àwọn ará Kenaani tí wọn ń gbé Araba, ní òdìkejì Giligali, lẹ́bàá igi Oaku More.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:30 ni o tọ