Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ègún ni fun yín bí ẹ kò bá tẹ̀lé òfin OLUWA Ọlọrun yín, tí ẹ bá yà kúrò lójú ọ̀nà tí mo pa láṣẹ fun yín lónìí, tí ẹ bá ń sin àwọn oriṣa tí ẹ kò mọ̀ rí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:28 ni o tọ