Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ibi tí ẹsẹ̀ yín bá tẹ̀, ẹ̀yin ni ẹ óo ni ín. Ilẹ̀ yín yóo bẹ̀rẹ̀ láti aṣálẹ̀ Lẹbanoni, ati láti odò Yufurate títí dé Òkun tí ó wà ní ìhà ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:24 ni o tọ