Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ẹ̀yin ati àwọn ọmọ yín lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun búra fún àwọn baba yín, pé òun yóo fún wọn títí lae, níwọ̀n ìgbà tí ojú ọ̀run bá wà lókè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:21 ni o tọ