Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tí ẹ bá tẹ̀lé òfin mi tí mo fun yín lónìí, tí ẹ fẹ́ràn OLUWA Ọlọrun yín, tí ẹ sì sìn ín pẹlu gbogbo ọkàn ati ẹ̀mí yín,

Ka pipe ipin Diutaronomi 11

Wo Diutaronomi 11:13 ni o tọ