Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 10:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni kí ẹ máa yìn, òun ni Ọlọrun yín, tí ó ṣe nǹkan ńláńlá tí ó bani lẹ́rù wọnyi fun yín, tí ẹ̀yin náà sì fi ojú ara yín rí i.

Ka pipe ipin Diutaronomi 10

Wo Diutaronomi 10:21 ni o tọ