Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

A máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn opó. Ó fẹ́ràn àwọn àlejò, a sì máa fún wọn ní oúnjẹ ati aṣọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 10

Wo Diutaronomi 10:18 ni o tọ