Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tí ń lọ níwájú yín ninu ọ̀wọ̀n iná lóru, ati ninu ìkùukùu lọ́sàn-án, láti fi ọ̀nà tí ẹ óo máa tọ̀ hàn yín kí ó lè bá yín wá ibi tí ẹ óo pàgọ́ yín sí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:33 ni o tọ