Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ tí Mose bá àwọn eniyan Israẹli sọ ninu aṣálẹ̀ nìyí, ní òdìkejì odò Jọdani, ní Araba tí ó kọjú sí Sufu, láàrin Parani, Tofeli, Labani, Haserotu ati Disahabu.

Ka pipe ipin Diutaronomi 1

Wo Diutaronomi 1:1 ni o tọ