Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá bẹ̀rẹ̀ sí bẹ OLUWA Ọlọrun tìrẹ̀lẹ̀-tìrẹ̀lẹ̀ mò ń gbadura tọkàntọkàn pẹlu ààwẹ̀; mo wọ aṣọ ọ̀fọ̀, mo sì jókòó sinu eérú.

Ka pipe ipin Daniẹli 9

Wo Daniẹli 9:3 ni o tọ