Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 9:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nisinsinyii, OLUWA Ọlọrun wa, ìwọ tí o kó àwọn eniyan rẹ jáde ní ilẹ̀ Ijipti pẹlu agbára ńlá, nítorí orúkọ rẹ tí à ń ranti títí di òní, a ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe nǹkan burúkú.

Ka pipe ipin Daniẹli 9

Wo Daniẹli 9:15 ni o tọ