Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 9:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí o sọ pé o óo ṣe sí àwa ati àwọn ọba wa náà ni o ṣe sí wa, tí àjálù ńlá fi dé bá wa. Irú ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí Jerusalẹmu yìí kò ṣẹlẹ̀ sí ìlú kan rí, ninu gbogbo àwọn ìlú ayé yìí.

Ka pipe ipin Daniẹli 9

Wo Daniẹli 9:12 ni o tọ