Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 8:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo tí ń ronú nípa rẹ̀, mo rí i tí òbúkọ kan ti ìhà ìwọ̀ oòrùn la gbogbo ayé kọjá wá láìfi ẹsẹ̀ kan ilẹ̀, ó sì ní ìwo ńlá kan láàrin ojú rẹ̀ mejeeji.

Ka pipe ipin Daniẹli 8

Wo Daniẹli 8:5 ni o tọ