Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 8:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára rẹ̀ yóo pọ̀, ṣugbọn kò ní jẹ́ nípa ipá rẹ̀, yóo máa ṣe àṣeyọrí ninu gbogbo ohun tí ó bá ń ṣe, yóo sì mú kí á run àwọn eniyan Ọlọrun ati àwọn alágbára.

Ka pipe ipin Daniẹli 8

Wo Daniẹli 8:24 ni o tọ