Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí èmi Daniẹli rí ìran náà, bí mo ti bẹ̀rẹ̀ sí wá ọ̀nà láti mọ ìtumọ̀ rẹ̀, ni ẹnìkan bá yọ níwájú mi tí ó dàbí eniyan.

Ka pipe ipin Daniẹli 8

Wo Daniẹli 8:15 ni o tọ