Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 6:26 BIBELI MIMỌ (BM)

mo pàṣẹ pé ní gbogbo ìjọba mi, kí gbogbo eniyan máa wárìrì níwájú Ọlọrun Daniẹli, kí wọ́n sì máa bẹ̀rù rẹ̀.“Nítorí òun ni Ọlọrun Alààyètí ó wà títí ayérayé.Ìjọba rẹ̀ kò lè parun lae,àṣẹ rẹ̀ yóo sì máa wà títí dé òpin.

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:26 ni o tọ