Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 6:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá pàṣẹ pé kí wọ́n lọ mú gbogbo àwọn tí wọ́n fi ẹ̀sùn kan Daniẹli, ati àwọn ọmọ wọn, ati àwọn aya wọn, wọ́n bá dà wọ́n sinu ihò kinniun. Kí wọn tó dé ìsàlẹ̀, àwọn kinniun ti bò wọ́n mọ́lẹ̀, wọ́n sì fọ́ egungun wọn túútúú.

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:24 ni o tọ