Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá sọ fún ọba pé, “Daniẹli, ọ̀kan ninu àwọn ìgbèkùn Juda kò kà ọ́ sí, kò sì pa òfin rẹ mọ́. Ṣugbọn ìgbà mẹta lóòjọ́ níí máa gbadura.”

Ka pipe ipin Daniẹli 6

Wo Daniẹli 6:13 ni o tọ