Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tọ́ ọtí náà wò, ó pàṣẹ pé kí wọn kó àwọn ife wúrà ati ti fadaka tí Nebukadinesari, baba rẹ̀, kó wá láti inú tẹmpili ní Jerusalẹmu jáde, kí òun, ati àwọn ìjòyè òun, àwọn ayaba ati àwọn obinrin òun lè máa fi wọ́n mu ọtí.

Ka pipe ipin Daniẹli 5

Wo Daniẹli 5:2 ni o tọ