Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 4:36 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní àkókò gan-an tí iyè mi pada bọ̀ sípò, ògo, ọlá, ati iyì ìjọba mi náà sì tún pada sọ́dọ̀ mi. Àwọn ìgbìmọ̀ ati àwọn ìjòyè mi wá mi kàn, wọ́n gbà mí tọwọ́ tẹsẹ̀, ìjọba mi tún fi ìdí múlẹ̀, mo sì níyì ju ti àtẹ̀yìnwá lọ ní gbogbo ọ̀nà.

Ka pipe ipin Daniẹli 4

Wo Daniẹli 4:36 ni o tọ