Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 4:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebukadinesari ní, “Lẹ́yìn ọdún meje náà, èmi, Nebukadinesari, gbé ojú sí òkè ọ̀run, iyè mi pada bọ̀ sípò. Mo yin Ẹni Gíga Jùlọ, mo fi ọlá ati ògo fún Ẹni Ayérayé.“Ìjọba ayérayé ni ìjọba rẹ̀láti ìrandíran ni ìjọba rẹ̀,àní, láti ìrandíran ni ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 4

Wo Daniẹli 4:34 ni o tọ