Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 4:32 BIBELI MIMỌ (BM)

a óo lé ọ kúrò láàrin àwọn eniyan, o óo máa bá àwọn ẹranko gbé, o óo sì máa jẹ koríko bíi mààlúù fún ọdún meje, títí tí o óo fi mọ̀ pé, Ẹni Gíga Jùlọ ní àṣẹ lórí ìjọba eniyan, ati pé ẹni tí ó bá wù ú ní í máa gbé e lé lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Daniẹli 4

Wo Daniẹli 4:32 ni o tọ