Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 4:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùṣọ́ náà pàṣẹ pé kí á fi gbòǹgbò igi náà sílẹ̀ ninu ilẹ̀; ìtumọ̀ rẹ̀ ni pé, dájúdájú, o óo tún pada wá jọba, nígbà tí o bá gbà pé Ọlọrun ni ọba gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Daniẹli 4

Wo Daniẹli 4:26 ni o tọ