Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 3:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn baálẹ̀ ìgbèríko, àwọn olórí, àwọn gomina, ati àwọn ìgbìmọ̀ ọba, kó ara wọn jọ, wọ́n sì rí i pé iná kò jó àwọn ọkunrin wọnyi, irun orí wọn kò rùn, ẹ̀wù wọn kò yipada, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò tilẹ̀ gbóòórùn iná lára wọn.

Ka pipe ipin Daniẹli 3

Wo Daniẹli 3:27 ni o tọ