Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún pàṣẹ pé kí àwọn akọni ninu àwọn ọmọ ogun rẹ̀ di Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego, kí wọ́n sì sọ wọ́n sinu adágún iná.

Ka pipe ipin Daniẹli 3

Wo Daniẹli 3:20 ni o tọ