Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pàṣẹ pé kí gbogbo àwọn baálẹ̀ agbègbè, àwọn olórí ati àwọn gomina, àwọn ìgbìmọ̀ ati àwọn akápò, àwọn onídàájọ́ ati àwọn alákòóso ati gbogbo àwọn òṣìṣẹ́ ọba tí wọ́n wà ní àwọn agbègbè Babiloni wá sí ibi ìyàsímímọ́ ère tí òun gbé kalẹ̀.

Ka pipe ipin Daniẹli 3

Wo Daniẹli 3:2 ni o tọ