Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba dá wọn lóhùn, pé, “Ohun tí mo bá sọ abẹ ni ó gé e; bí ẹ kò bá lè rọ́ àlá náà fún mi, kí ẹ sì sọ ìtumọ̀ rẹ̀, n óo fà yín ya ní tapá-titan, ilé yín yóo sì di àlàpà.

Ka pipe ipin Daniẹli 2

Wo Daniẹli 2:5 ni o tọ