Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 2:47 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba sọ fún Daniẹli pé, “Láìsí àní àní, Ọlọrun rẹ ni Ọlọrun àwọn ọlọrun, ati OLUWA àwọn ọba, òun níí fi ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ han eniyan, nítorí pé àṣírí ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ yìí gan-an ni o sọ.”

Ka pipe ipin Daniẹli 2

Wo Daniẹli 2:47 ni o tọ