Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 2:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn rẹ ni ìjọba mìíràn yóo dìde tí kò ní lágbára tó tìrẹ. Lẹ́yìn èyí ni ìjọba kẹta, tí ó jẹ́ ti idẹ, yóo jọba lórí gbogbo ayé.

Ka pipe ipin Daniẹli 2

Wo Daniẹli 2:39 ni o tọ