Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Daniẹli 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ọba pàṣẹ pé kí wọ́n pe àwọn pidánpidán, ati àwọn aláfọ̀ṣẹ, àwọn oṣó ati àwọn ará Kalidea jọ, kí wọ́n wá rọ́ àlá òun fún òun. Gbogbo wọn sì wá siwaju ọba.

Ka pipe ipin Daniẹli 2

Wo Daniẹli 2:2 ni o tọ